Take a fresh look at your lifestyle.

Orílẹ̀-eldè Nàìjíríà yóò ṣagbáterù ìpàde àpérò láti kojú ìṣúná ọ̀nà àìtọ́

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

34

Ìjọba Nàìjíríà ti parí àwọn ètò láti ṣe àpèjọ káríayé ọlọ́jọ́ méjì lórí àtikojú ìsúná ọ̀nà àìtọ́ (IFFs) àti gbíí́gba dúkìá ìlú tíwọn ṣe báṣubàṣu padà.
Ajọ to nrisi idẹkun iwa ibajẹ ati iru awọn iwa to jọọ ni yoo gbalejo apejọ naa.
Alaye atẹjade kan, lati ọdọ agbẹnusọ ajọ to nrisi idẹkun iwa ibajẹ ati iru awọn iwa to jọọ,iya aafin Azuka Ogugua,sọ pe,minisita fun isuna,inawo ati eto orilẹ-ede,iya aafin Zainab Ahmed,ni yoo jẹ olusọrọ isaaju nibi apejọ gbogbogboo naa.
Awọn eniyan pataki ti yoo wa nibi apejọ naa ni,agbẹjọro agba fun orilẹ-ede to si tun jẹ minisita fun idajọ,Ọgbẹni Abubukar Malami,SAN;Minisita fun ọrọ okeere,Geoffrey Onyema,kọmisọna fun ọrọ oṣelu adulawọ,alaafia ati aabo,aṣoju Bamikọle Adeoye ati oludamọran agba fun aarẹ lori idajọ,Juliet Ibekaku-Nwagwu ati awọn olukopa pataki miran lati agbaye.

Leave A Reply

Your email address will not be published.