Take a fresh look at your lifestyle.

Enugu:Àwọn jàǹdùkú dáná sun olú ilé-iṣẹ́ àjọ t́i ó ńṣàmójútó ètò ìdìbò

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

39

Ile iṣẹ ajọ to nmojuto eto idibo[INEC]ti ke gbajari pe awọn janduku kan ti dana sun ọkọ Hilux mẹfa ni olu ile-iṣẹ wọn ni ọjọ aiku.

Kọmiṣọna apapọ ati alaga , oluṣakoso ati Igbimọ idanilẹkọ awọn oludibo[INEC],agbẹjọro Festus Okoye fi idi ẹ mulẹ ninu atẹjade kan ti o jade ni ọjọ aje.

Gẹgẹbi Igbimọ naa, Komisona idibo ti INEC (REC) fun Ipinle Enugu, Emeka Ononamadu, ṣe ijabọ ikọlu naa si olu  Ile-iṣẹ ọhun  ni alẹ ọjọ aiku ,oṣu Karun,ọjọ kẹrin din-logun,ọdun  2021.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.