Take a fresh look at your lifestyle.

Igbákejì ààrẹ ,Yẹmí Òsínbàjò gbóṣùbà káre láí fún ilé-iṣẹ́ onímọ̀ ẹ̀rọ SecureID

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

151

Igbákejì ààrẹ, Ọ̀jọ̀gbọ́n Yẹmí Ọ̀sínbàjò, ti gbóríyìn fún  SecureID Limited, tí ójẹ́  olùpìlẹ̀ṣẹ̀ alákọ́kọ́ ìwé pélébé alásọdowó tiwantiwa , fún fífi ìlànà kalẹ̀ fùn àwọn ilé-iṣẹ́ Nàìjíríà míràn láti tẹ̀lé.

Osinbajo gbe oṣuba fun ile-iṣẹ SecureID naa ni ọjọ iṣẹgun nigbati o ṣe abẹwo si ile-iṣẹ naa ti owa ni isọlọ, ni ilu Eko.

Ọjọgbọn naa ṣe akiyesi pe,ile-iṣẹ ọhun ti jẹ awokọṣe olupese anfaani iṣẹfun awọn ọmọ orilẹ-ede ati pe o tun jẹ ki orilẹ-ede o fakọ yọ lati le figbagbaga pẹlu awọn iru ile-iṣẹ bẹẹ lagbaye.

O ṣe sadankata fun ile-iṣẹ naa lori Iwe-ẹri agbaye ti awọn ohun elo alagbeka agbaye (GSMA) ti o gba laipẹ , oṣe  afikun pe laiseaniani eyii yoo mu ọpọlọpọ awọn anfaani ba orilẹ-ede.

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.