Take a fresh look at your lifestyle.

Eid -Al-Fitr:Pàtàkì ni ìṣọ̀kan jẹ́ láàrin ọmọnìyàn

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

101

 

 

Ààrẹ Mùhámmádù Bùhárí  kí  gbogbo àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè Nàíjíríà àti àwọn Mùsùlùmí káàkiri àgbáyé bí wọ́n ṣe ńṣe ayẹyẹ Eid Al- Fitr lẹ́yìn ìparí oṣù ààwẹ̀, nínú àtẹ̀jáde kan tó buwọ́ lù.

Gẹgẹ bi aarẹ naa, o jẹ ǹkan àrítọ́kasí ati  idunnu lati ri pe, awọn kristẹni nṣinu aawẹ  pẹlu awọn musulumi ati pe, nigbamiran, wọn tun nawọ oore ati ẹbun si awọn musulumi ododo lakoko Ramadan.

isokan  ara ilu: ẹlẹsin Musulumi ati  Kristiani ṣe pataki paapaa ni akoko  ti orilẹ-ede wa dojukọ ọpọlọpọ awọn iṣoro, eyiti a le bori nikan, nigbati a ba  fimọ ṣọkan.

Aarẹ Buhari wa rọ awọn ọmọ Naijiria lati tẹsiwaju nipa ṣiṣe akiyesi gbogbo awọn igbese idena aarun COVID, ati lati ṣe ajọyọ naa niwọnba lakoko  isinmi.

 

 

 

 

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.