Take a fresh look at your lifestyle.

Gàmbàrí bẹnu àtẹ́ lu ìṣẹ̀lẹ̀ ìdìgunjalè tó wáyé ní Víllà

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

121

Ilé-iṣẹ́ ààrẹ ti fìdí ẹ̀ múlẹ̀ wípé , àwọn ọlọ́sà gbìyànjú láti jalè ní ibùgbé olórí àwọn òṣìṣẹ́ ilé-iṣẹ́ ààrẹ Bùhaŕí,Ìbràhím Gàmbàrí.

Agbẹnusọ fun ile-iṣẹ aarẹ fi   daniloju pe iṣẹlẹ naa waye  ni alẹ ọjọ aiku lori ẹrọ aye lujara.

Gambari  bẹnu atẹ lu iṣẹlẹ ọhun, ti o waye ni ọganjọ oru ni deedee agogo mẹta.

Sugbọn, sibẹsibẹ, pabo ni iṣẹlẹ naa jasi.

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.