Take a fresh look at your lifestyle.

Ààrẹ Buhari ń sèpàdé pẹ̀lú àwọn adarí àjọ elétò ààbò

180

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Muhammadu Buhari ń sèpàdé pẹ̀lú àwọn adarí àjọ elétò ààbò nile aarẹ , Villa, to wa niluuAbuja.

ipade ọhun lo bẹrẹ ni deede aago mẹsan an owurọ oni, ni ọfiisi iyawo aarẹ to wa niluu Abuja..

lara awọn to wa nibi ipade ọhun niigbakeji aarẹ orilẹ ede Naijiria,Yemi Osinbajo, adari osisẹ aarẹ , Ibrahim Gambari  ati oluranlọwọ aarẹ lori eto aabo , ajagunfẹyinti Babagana Monguno.

lara awọn to tun wa nibi ipade ọhun ni adari gbogbo ajo eleto aabo, ọgagun Lucky Irabor ati adari ile-isẹ ọlọpaa lorilẹ ede Naijiria, Usman Baba.

Ipade yii waye lati jiroro lori bi eto aabo to mẹhẹ lorilẹ ede Naijiria yoo se fẹsẹ mulẹ.

Leave A Reply

Your email address will not be published.