Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ ò tó, ẹ lọ pọ̀ si wá:Chelsea gé ìyẹ́ apá Man City nínú àṣekágbá Champions League

Ademọla Adepọju

114

Lọ́jọ́ Àbámẹ́ta  yìí ni ikọ̀ agbabọọlu Chelsea  kó pàsán ìyà lu ikọ̀ Manchester City , nínú ìdíje bọ́ọ̀lú à-fẹsẹ̀gbá tó wáyé ní  pápá ìṣeré Etihad.

Ìyà ẹgba meji (2) pere ni ikọ̀ agbabọọlu Chelsea fun ikọ̀ agbabọọlu Manchester City, ti ikọ agbabọọlu Chelsea naa si fara káásá iya ẹgba kan(1) , sé ìyà díẹ̀-díẹ̀ ló ń jòkú ìgbẹ́

Amọsa, ọjọ kọkandinlọgbọn oṣu karun un ní wọn mejeeji yoo  pade ninu ifẹsẹwọnsẹ aṣekagba idije Champions League.

Ademọla  Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.