Take a fresh look at your lifestyle.

Ikú dóró! Dare Adeboye dágbere fáyé pé, ó dìgbóse- Ààrẹ Buhari banújẹ́

136

Ààrẹ  Muhammadu Buhari ti bá àwọn ẹbi, olùdarí ìjọ ìràpadà (the Redeemed Christian Church of God ,RCCG),pasitọ Enoch Adeboye,kẹ́dùn lórí ikú ọmọkùnrin rẹ̀ ,Pasitọ Dare Adeboye.

Bakan naa ni aarẹ tun ba awọn ọmọ ijọ irapada ti ẹkun naa kẹdun pe ki wọn maa se banujẹ sugbọn ki wọn maa gba ara wọn niyanju  nipa ẹmi mimọ  ati pe gbogbo awọn ti wọn ba n sin Ọlọrun ni otitọ ati ododo  yoo ri i ni ọjọ Ajinde.

 

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.