Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà ti Ṣetán Láti Dín Owó ìṣàkóso ìjọba kù

117

Ìjọba Nàìjíríà ti sọ pé òhun  yóò ṣe àtúnyẹ̀wò owó àwọn òṣìṣẹ́ àti  àwọn ilé iṣẹ́ rẹ̀ nípasẹ̀ àti dín owó ìsàkóso ìjọba kù .

Minisita fun eto inawo, eto isuna ati eto ilu, Iyaafin Zainab Ahmed kede eleyi nibi jomitoro ọrọ  lori iwa ibajẹ ati  inawo iṣejọba ni orilẹ-ede Naijiria ti a ṣeto nipasẹ Igbimọ Aṣoju  Ominira (ICPC) ni ilu Abuja.

Iya aafin Ahmed ṣe alaye pé Ààrẹ Muhammadu Buhari ti kan nipa fun  ìgbìmọ ti o nrisi owo oṣù sisan láti mú ìlànà àyẹ̀wò náà wa ṣiṣẹ.

 

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

 

Leave A Reply

Your email address will not be published.