Take a fresh look at your lifestyle.

Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin ṣe ìlérí Láti ripé àwọn ọmọ ilé-ìwé t́i wọ́n jígbé gba ìtúsílẹ̀.

98

Àwọn ọmọ ilé ìgbìmọ̀ Aṣojú ti pinnu láti sowọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn tó tọ́ nípa gbígba ìtúsílẹ̀ àwọn ọmọ ilé-ìwé tí wọ́n j́igbé ní Yunifásítì Greenfield ní Ìpínlẹ̀ Kaduna.
Abẹnugan ile igbimọ aṣofin naa, Ọgbẹni Femi Gbajabiamila ti ṣe adehun fun awọn obi awọn ọmọ ile-iwe ti wọn fipa jigbe to nfẹhonu han ni apejọ kan ni ilu Abuja.
Ọgbẹni Benson ti o jẹ olori agbẹnusọ fun awọn obi sọ pe, awọn gbọkanle igbimọ asofin nipa gbigba itusilẹ awọn ọmọ wọn,idi eyi ni wọn ṣe ke gbajari wa bawọn.
Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Leave A Reply

Your email address will not be published.