Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ máa dábàá láti yọ ààrẹ Buhari nípò -Ilé- iṣẹ́ ààrẹ

73

Ile-iṣẹ  aarẹ ti kilọ fun awọn eniyan ti wọn n sara wọn jọ lati da wahalaa silẹ lorilẹ ede Naijiria , ti wọn si tun n lu ilu , kó bẹ́, ko bẹ́ , lati aarẹ Muhammadu Buhari kuro nipo aarẹ.

ile isẹ aarẹ tun  ṣalaye itaniji ti o wa lati ẹka awọn ipinlẹ ti o gbe jade ni ipari osẹ, gẹgẹ bi itọka si igbimọ awọn amọtara ẹni nikan ,ti o fẹ fipa yi ijọba pada lọna aitọ.
oldamọran aarẹ lori iroyin ati ikede fẹmi Adesina sọ pe ijọba mọ pe awọn oloselu onimọtara-ẹni-nikan ti n ṣa awọn adari ẹya kan jọ ,lati kopa nibi idibo lati yọ aarẹ Muhammadu Buhari.

 

 

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Leave A Reply

Your email address will not be published.