Take a fresh look at your lifestyle.

Ìjọba Nàìjíríà dá Ilé-iṣẹ́ Fún Ìṣàkóso Àwọn ohun-ìjà oogun sílẹ̀

89

Ààrẹ orílẹ̀-ede Nàìjíríà, Mùhámmádù Bùhárí ti fọwọ́sí ìdásílẹ̀ Ilé-iṣẹ́ fún ìṣàkóṣo àwọn ohun-ìjà ogun  kékèré , NCCSALW,t́i ilé-iṣẹ́ oludamọ̀ràn fun aarẹ lori eto  ààbò lOrílẹ̀-ede yii yoo maa sakoso rẹ.
Oludari eto fun iroyin  ati ibaraẹnisọrọ,Ọgbẹni Zakari Usman, lo  sọ eleyii ni ilu Abuja ni ọjọ Aiku.
Usman sọ pe NCCSALW ti rọpo Igbimọ alakoso ti o pari lori SALW ati pe yoo ṣiṣẹ bi ilana igbekalẹ fun itọsọna eto imulo, iwadi ati abojuwo gbogbo awọn ẹya ti SALW .

Usman tun ṣafikun pe Aare Buhari ti yan ajagunfẹyinti AM Dikko, gẹgẹ bi  Alakoso  akọkọ fun ile-iṣẹ naa.

 

 

Eyitayọ Fauziat Oyetunji

Leave A Reply

Your email address will not be published.