Take a fresh look at your lifestyle.

Chidinma di akọrin ìhìnrere

Ademọla Adepọju

49

Akọrin ìlú  mọ̀-ọ́n-ká , tó jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà, Chidinma  ti kéde lórí ẹ̀rọ Instagram rẹ̀ lásìkò tó ń se ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgbọ̀n ọdún rẹ̀ pé òun ti di  ” ONÍWÀÁSÙ IHINRERE TI JESU KRISTI.”

Lọdun 2010,nigba ti  Chidinma pe ọmọ ọdun mọkandinlogun (19) ni o di ilu mọ-ọn-ka lasiko to gba ife ẹyẹ  Project Fame West Africa .  Lẹyin naa ni o kọrin kan to pe ni , ‘Jankoliko’ ninu orin ti o kọ pẹlu akọrin , Sound Sultan.

lẹyin naa ni  o bẹrẹ si n kọrin fun  ile -isẹ  iLLBliss  Clarence Peters‘ , Capital Hill/Goretti k , .’  o tun  kọrin  kan  ti o pe akọle rẹ ni  ‘Emi Ni Baller,’ ni eyi to gba ife ẹyẹ Headies  lọdun  2014 .

 

lọdun  2012 ni o tun gba ife ẹyẹ  KORA , gẹgẹ bi akọrin obinrin to mọ orin kọ julọ nilẹ Afirika. O tun wa lara awọn ti Ile-isẹ  MTV Africa fun ni ife ẹyẹ  gẹgẹ bi akọrin obinrin to mọ orin kọ julọ lọdun  2014.

Leave A Reply

Your email address will not be published.