Take a fresh look at your lifestyle.

Mi ò ní sinmi,àyàfi tí àlàáfíà bá jọba lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà-Ààrẹ Buhari

Ademọla Adepọju

60

Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàíjíríà.Muhammadu Buhari, ti ní ìjọba rẹ̀ yóò sa gbogbo ipá rẹ̀ láti fòpin sí gbogbo ìwà ibi tó ń sẹlẹ̀ ní àwọn apá ibìkan lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà kí ètò ààbò leè joba lórílẹ̀ èdè yii.

Oluranlọwọ aarẹ lori eto aabo, ajagunfẹyinti Babagana Monguno, lo sọrọ yii lẹyin ipade ti aarẹ se pẹlu awọn adari ajọ to n mojuto eto aabo lorilẹ ede Naijiria, lọjọ Ẹti niluu Abuja.

Monguno ni ”Aaarẹ lo pe ipade yii latari awọn ipenija to n sẹlẹ lori eto aabo ni awọn apá ibikan lorilẹ ede yii.”

”Aarẹ ti gbaradi  lati gbe igbesẹ to lagbara ni eyi lati fopin si iwa janduku, ipaniyan ati ijinigbe to n waye ni awọn apa ibikan lorilẹ ede Naijairia.

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.