Take a fresh look at your lifestyle.

Ẹ seun, ti ẹ̀ ò jẹ́ kí òógùn alábàárù gbẹ- Comrade Olusegun Abatan

Abiọla Olowe

71

Akọ̀wé  ẹgbẹ́ òsìsẹ fẹ̀yìntì ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Comrade Olusegun Abatan fi orin ìdúpẹ́ lu gomina Seyi Makinde lọgọ ẹnu fún isẹ́ takuntakun tó ń se, ní pàtàkì jùlọ nípa Sísan  owó ìfẹ̀yìntì wọn lásìkò.

Eleyii lo faa ti awọn osisẹ fẹyinti lọkunrin ati lobinrin naa wa fi idunnu wọn han pe ayajọ ọjọ osisẹ ti ọdun yii naa s’oju ẹ̀mí wọn.

Lara awọn ẹgbẹ osisẹ to peju sibẹ ni ,awọn osisẹ ijọba, awọn olokoowo, awon olukọ, awọn ẹgbẹ onisẹ owo,  agbẹ ati bẹẹ bẹẹ lọ.

 

 

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.