Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ̀ Asòfin Orílẹ̀ èdè Hong Kong yóò jíròrò lórí òfin ìwé ìgbélùú

92

Ilé ìgbìmọ̀ asòfin ti Hong Kong ti ní àwọn ti setán láti jíròrò lórí ìwé àbádòfin ìgbélùú tí àwọn agbẹjọ́rò, àwọn asojú orílẹ̀ èdè  àti àwọn a-jà -–ẹ́tọ̀ọ́-ọmọnìyàn sọ pé yóò fún ìjọba orílẹ̀ èdè náà ni agbára tí kò lópin , ní èyí tí yóò  se ìdíwọ́ fún àwọn olúgbè àti àwọn ènìyàn tó bá fẹ́ wọnú ìlú náà tàbí kúrò nílùú ti àwọn ọmọ orílẹ̀ èdè China n sakoso níbẹ̀.

ijọba orilẹ ede naa, ti ni ki awọn eniyan maa se bẹru , wi pe iwe abadofin naa wa lati gbogun ti awọn eniyan ti ko ni iwe igbeluu ati lati se isẹ fini-fini lori awọn ti wọn fẹ gba iwe lati se atipo lorilẹ ede naa.

 

 

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.