Take a fresh look at your lifestyle.

ìdùnnú subú layọ̀,ìpínlẹ̀ mẹ́rin ni yóò jàǹfààní owó gọbọi fún okòòwò adìẹ

102

Ìgbìmọ̀ ìjọba àpapọ̀ ti fọwọ́sí owó gọbọi tó  lé ní ẹgbẹ̀ta miliọnu( N665.2 ) fún isẹ́ àkànse láti mú idagbasoke ba ètò ohun abìyẹ́  ní àwọn ìpínlẹ̀  Borno, Plateau, Yobe àti Zamfara.

Minisita fun eto ọmọniyan, gbigbogun ti ajalu ati idagbasoke  iwajọ, Sadiya Farouk lo sọrọ yii pẹlu awọn akọrọyin ile aarẹ lẹyin ipade igbimọ ijọba to waye lọsẹ yii , ni eyi ti aarẹ  Muhammadu Buhari dari rẹ.

o tẹsiwaju pe eto ohun abiyẹ yii wa lati pese eto iranwọ fun awọn eniyan ti ajalu de ba lọdun 2019 ni awọn ipinlẹ mẹrin wọnyi.

 

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.