Take a fresh look at your lifestyle.

COVID-19: Àwọn ènìyàn mẹ́rìndínlọgọ́jọ míràn tún jẹyọ

106

Àwọn ènìyàn mẹ́rìndínlọgọ́jọ miran tun jẹyọ ti wọn ni aarun  COVID-19, lorilẹ ede Naijiria , ni eyi ti o fi jẹ ki apapọ gbogbo awọn to ni aarun ọhun jẹ 164,912.

Ajọ to n mojuto ajakalẹ aarun lorilẹ ede Naijiria iyẹn ,Nigeria Centre for Disease Control (NCDC) lo kede rẹ lori ẹrọ  Twitter wọn pe ipinlẹ mọkanla( 11 ) ni aaarun COVID-19 ti jẹ yọ , Eko aadọta (50) , Enugu  mẹtalelogoji( 43) nigba ti  Jigawa, Kaduna, Oyo ati ipinlẹ Rivers  ni ẹyọkan( 1 )

ajọ naa tun kede pe iye aọwn eniyan ti aarun Korona ti pa lorilẹ ede yii jẹ mẹ́tàlélọ́gọ́tale ni ẹgbẹrun meji(2,063) ti awọn  eniyan mejilaleniẹgbẹrun márùndínlọgọ́jọ(155,012) ṣi ti gba iwosan.

 

 

 

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.