Take a fresh look at your lifestyle.

Ìgbìmọ ológun orílẹ èdè Chad yan adarí ìgbìmọ ìjọba tuntun

53

Adarí ìjọba àná , Albert Pahimi Padacke, ti o mú ipò kejì níbi ètò ìdìbò ààrẹ  tó wáyé ní ọjọ́ kọkànlá , Osù kẹrin lórílẹ̀ èdè Chad , ni wọ́n ti yàn gẹ́gẹ́ bí  adarih ìgbìmọ̀ tuntun  fún orílẹ̀ èdè ọ̀hún.

Iroyin naa waye ninu atẹjade kan ti awọn igbimọ ologun orilẹ ede naa gbe jade  lọjọ Aje.

Iroyin lẹkununrẹre n bọ lori laipẹ…

 

Ademola    Adepoju

Leave A Reply

Your email address will not be published.