Take a fresh look at your lifestyle.

Èèmọ rèé; ìkọlù àdó olóró ní Somalia

Adémọ́lá Adépọ̀jù

66

Lọjọ Àìkú yìí ni ikọ ọmọ ogun ìjọba orílẹ èdè Somalia àti ikọ ọmọ ogun ọlọtẹ bẹ̀rẹ̀ sì n rọ òjò àdó olóró àti ìbọn a-ta ma-tase si ara wọn látàrí bí ààrẹ orílẹ̀ èdè ọ̀hún ,Mohamed Abdullahi se fi àáké kọ́rí láti sún ètò ìjọba rẹ̀ síwájú síi.
Bo tilẹ jẹ pe ko si akọsilẹ iye awọn eniyan to ti gbẹmi mi sibẹ ọgọọrọ awọn ikọ ọmọ ogun ijọba aarẹ Mohamed Abdullahi lo duro si awọn aarin gbungbun orilẹ ede naa.
Saaju eyi , lọjọ Aiku ni ọgọọrọ ọmọ orilẹ ede ọhun bọ si oju popo lati fẹhonuhan , timwọn si n kọrin pe ‘ awon ko fẹ ijọba apanirun, ijọba kanpa mọ’ bakan naa ni wọn tun dana sun ère aarẹ Mohammed.

Ademọla Adepọju

Leave A Reply

Your email address will not be published.