Take a fresh look at your lifestyle.

Covid-19: Àwọn ènìyàn mẹ́tàdínlógójì ààrùn míràn tún ti jẹyọ

Ademọla Adepoju

114

Àwọn ènìyàn mẹ́tàdínlógójì (37) míràn tún ti jẹyọ tí wọ́n ní ààrùn Korona lórílẹ̀ èdè Nàíjíríà báyìí.Ní èyí, tí ó jẹ́ ki iye àwọn ènìyàn tí ó ní  ààrùn COVID19  jẹ ọgọrun un kan ati ọgọta le mẹrinlelaadọta(164,756) ti iye awọn eniyan to ti gba iwosan si jẹ  mẹrinlelaadọtalelọgọrun ati  mẹsanlelọgọta(154,963) nigba ti awọn eniyan  Ọgọtamejilelẹgbẹrun meji(2,062 ) si ti kú.

Gẹgẹ bi ajọ to n gbogun ti ajakalẹ aarun lorilẹ ede Naijiria  NCDC se sọ pe ,awọn ipinlẹ mẹfa ni awọn eniyan to ni aarun COVID-19 ti jẹyọ awọn ipinlẹ naa ni;  ”Eko-26, Ogun-4, Kaduna-2, Rivers-2,  Kwara-2 and Edo-1.”

Leave A Reply

Your email address will not be published.